Alujanjankijan

Sola Allyson, Adekunle Gold

Iya iya ta'kun wa'le alujanjankijan Iya iya ta'kun wa'le alujanjankijan E ma f'omo s'ile fun'ya je alujanjankijan Eni t'o bi'mo lo ye k'o w'omo alujanjankijan Ba mi n'omo mi o ye k'o de'nu olomo Oju merin lo n bi'mo sugbon igba oju li n w'omo Omo t'a o ko a gbe'le t'a ko ta Omo t'a o to a k'eso t'a ni ta Omo n'igbeyin omo l'ola omo l'ola omo n'iyi omo l'ade Omo l'ewa omo l'eso oh ohhh O da a bi o da a o le da a o san bi o san a de san Igboya at'adura ni o gba yi o da ahhh Iya iya ta'kun wa'le alujanjankijan Iya iya ta'kun wa'le alujanjankijan E ma f'omo s'ile fun'ya je alujanjankijan Eni t'o bi'mo lo ye k'o w'omo e e t'omo alujanjankijan Ori fun wa l'omo're bi i ti Samuel oh Won ko Samu o gb'eko oh o si se'hun rere If you spare the rod you go spoil the child I hope you know Train them with the love of God abegi oh Tori alaigboran omo- asa ni Agba o kunwo l'oju- asa ni Agba o jo won l'oju oh- asa ni Agba iya ni o da- asa ni Alalugboran omo oh- omo ni Won le d'eyan l'ola- omo ni T'a ba to won daada o- omo ni Won le d'eyan l'ola Iya iya ta'kun wa'le oh alujanjankijan Iya iya ta'kun wa'le oh alujanjankijan Eni t'o bi'mo lo ye k'o w'omo oh alujanjankijan E ma f'omo s'ile fun'ya je oh alujanjankijan Iya iya ta'kun wa'le oh ohoh alujanjankijan E ma f'omo s'ile fun'ya je oh oh alujanjankijan Eni t'o bi'mo e lo ye k'o w'omo e e t'omo alujanjankijan Iya baba t'akun wa'le alujanjankijan Kekere la tin gbe ka iroko to ba dagba tan ebo ni o ma gba Ohun tai ba fi sile ni ewure gbe ke ewure ayie ko ma a gbe wa lo mo lo Omo taa ba to ekun aiye agbe lo ke ekun aiyie maa ma gbe wa lo mo lo Iya iya ta'kun wa'le oh alujanjankijan Iya iya ta'kun wa'le oh oh alu jan jan jan Iya iya ta ah ah ah alujanjankijan Iya iya t'akun wa'le alujanjankijan Eledumare ko ba wa tun omo wa oh alujanjankijan eledumare ko ba wa tun omo wa oh Children are the heritage of the lord alujanjankijan E gbo omo lo la omo layie omo le wa alujanjankijan Omo le re ka fa ye se le ka tan omo wa oh oh oh alujanjankijan They are the future generation alujanjankijan Iya iya ta'kun wa'le alujanjankijan alu jan jan ki jan

Written by: ADEKUNLE KOSOKO, SOLA ALLYSON OBANIYILyrics © Sony/ATV Music Publishing LLCLyrics Licensed & Provided by LyricFind

Create your own version of your favorite music.

Sing now

Kanto is available on:

google-playapp-storehuawei-store