Owo Dollar

Seriki, Obesere

By fire by force we must shine (Seriki) Obesere ati seriki lowa ninu ogba yii Won leni Kan n gbemu Ta lon gbemu? She e mo bi won she n nawo ni? Owo dollar lo n na (Lo n na) Aso dollar lo n wo (Lo n wo) Ounje dollar lo n je At the same time (Igbe dollar lo n ya) Owo dollar lo n na (Lo n na) Aso dollar lo n wo (Lo n wo) Ounje dollar lo n je At the same time (Igbe dollar lo n ya) Seriki omo owo (O n ya dollar) IBD dende ( O n ya dollar) Hushpuppi ( O n ya dollar) Deji Tinubu ( O n ya dollar) M.C oluomo ( O n ya dollar) Niyass ( O n ya dollar) Wale bouncer ( O n ya dollar) Alhaji Abass Akande ( O n ya dollar) See bami pe dolapo ko maa bo Ko WA gbo nkan ti mo babo To ba de ti n bo ko pelabo Tori laleyi o maa konsolijapo O sha ti ri, awon ti mo ba to Omo pe Bentley on she egbe Prado Fine girl obrigado Ma lo bawon gbenu si kolorado Bi mo she n bosu mo ma n wonder Ma wule laagun jina ma bother Wo nkan to ba fe je ni ko order Omo gbagbe pe eeyan kan ti lo ti border Eni eji eta nkan te she se mo pe koda E fun mi lorobo e mu lepa Orobo ke agbara mi o ka Owo dollar lo n na (Lo n na) Aso dollar lo n wo (Lo n wo) Ounje dollar lo n je At the same time (Igbe dollar lo n ya) Owo dollar lo n na (Lo n na) Aso dollar lo n wo (Lo n wo) Ounje dollar lo n je At the same time (Igbe dollar lo n ya) Wale Alagbon (O n ya dollar) Godfather ( O n ya dollar) Aremo Oniru ( O n ya dollar) Baddy Osha ( n ya dollar) Abu Abel ( O n ya dollar) Dammy Richie ( O n ya dollar) Oba Bombay( O n ya dollar) Alhaji Abass Akande ( O n ya dollar) Owo mo wa na mi o wa ya photo Mi o wa ya photo Seriki o wale o de yoo jo O ni wale o de ni yoo jo See aa ni payan owo la maa pa Yee maa wo bi omoge she yapa Won wo bikini o,tun wo kaba E ma pa baba oni baba A n soro hard currency Make I dey eat your work honestly E gbegbe ti gbegbe Gbe sumo mi kin fowo kan bebe Fine girl unanugo Owo wa n le ma lo dami duro Coronavirus o kin pamugbo Ma lo deru kinni nla barugbo Owo dollar lo n na (Lo n na) Aso dollar lo n wo (Lo n wo) Ounje dollar lo n je At the same time (Igbe dollar lo n ya) Owo dollar lo n na (Lo n na) Aso dollar lo n wo (Lo n wo) Ounje dollar lo n je At the same time (Igbe dollar lo n ya) Baakole (O n ya dollar) Hundred percent ( O n ya dollar) Obafemi martins ( O n ya dollar) Tejumola Jerry ( O n ya dollar) Idris perpay ( O n ya dollar) Ade Benz ( O n ya dollar) Kolawole edun ( O n ya dollar) Alhaji Abass Akande ( O n ya dollar) O n ya dollar O n ya dollar O n ya dollar O n ya dollar O n ya dollar O n ya dollar O n ya dollar O n ya dollar

Written by: Lyrics © TuneCore Inc.Lyrics Licensed & Provided by LyricFind

Create your own version of your favorite music.

Sing now

Kanto is available on:

google-playapp-storehuawei-store