Iya Alariya

9ice

Emi ni kan kan mow a Moni baba ni gbejo Mo wowo ra mo gbagbe iyin ola ati egan Iya laari ya ken ken eh Iya laari ya ken ken eh eh Iya laari ya ken ken ma jo mayo Iya laari ya ken ken eh eh Ti mob a lo pelu imo kan Taabi mo re koja lo pelu inu kan Sa dede ni blessing awa si odo mi toori mo gbagbo Egbegberun subun lotun loosi me Nkan kan koni se omo olorun Okeere opoju temi Emi nikankan mow a Moni baba ni igbejo Emi ni kan kan mow a Moni baba ni gbejo Mo wowo ra mo gbagbe iyin ola ati egan Iya laari ya ken ken eh Iya laari ya ken ken eh eh Iya laari ya ken ken ma jo mayo Iya laari ya ken kеn eh eh Ise owo mi koni di ibajе Won tie muruwu muruw mo mi Wan ko fe te o Bab ti se ileri pe ma jaiye mi pe pe pe pe Atele ese n te ono Ajoke aiye, asake orun koni si mi lono Eye se inu binu si mi ma Mo ni baba ni igbejo Emi ni kan kan mowa Moni baba ni gbejo Mo wowo ra mo gbagbe iyin ola ati egan Iya laari ya ken ken eh Iya laari ya ken ken eh eh Iya laari ya ken ken ma jo mayo Iya laari ya ken ken eh eh

Written by: Lyrics © TUNECORE INC, TuneCore Inc.Lyrics Licensed & Provided by LyricFind

Create your own version of your favorite music.

Sing now

Kanto is available on:

google-playapp-storehuawei-store